E wo arakunrin Toyin Agbetu! Awon ni oga ni aparapo ilosiwaju egbe Afika www.ligali.org.
E wo bi won nshe igbega gbogbo eniyan Afrika to shalaisi ni Maafa!! Won so fun awon Yurugu Elisabeth 1 ti Windsor, iyaafin England, ati Anthony Blair, oga UK pelu awon ara won nipa iwaburuku ti won ti she sile.
Kosi gbagbe. Kosi foriji.
eworan
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment