Monday, November 13, 2006

Securing Africa

David McCormack nshe ishe ni Center for Security Policy, nibiti o ti dari Eto African Security. Iwe re lori idimu ashode Africa fi ijamba han ti ole ba awon ilowosi t'ipinle USA ni ile Africa. Ijamba na gbera lati eshu 'Islamofascism' ati iwa ipinle China. Iwe na soro nipa bi Somalia, Nigeria and South Africa she le baraje nibuburu. Iwe na ko soro nipa Sudan, ni ibi ti ijoba omo-Arab ti n'pa awon eniyan omo-Africa, ti won le won kuro ni ile, ti won ba awon omobirin ati omode won je pelu f'agbara do ati imu'leru. Afigba ti USA ba ran Yoruba lowo lati gba ogbon-ibon ati le Sharia kuro ni Nigeria, ilu na le di ile Taliban bi Somalia she ri ni isiyin. Ethopia nikan o le di Somalia ati Eritrea mu ninu ija lati le Taliban kuro ni awon ilu 'Islamofacism' yen.

http://www.centerforsecuritypolicy.org/index.jsp?section=papers&code=06-F_27

No comments: